-
Ẹ́kísódù 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, Mósè àti Áárónì wọlé lọ bá Fáráò, wọ́n sì sọ fún un pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Jẹ́ kí àwọn èèyàn mi máa lọ, kí wọ́n lè ṣe àjọyọ̀ fún mi nínú aginjù.’”
-