ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 3:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Ó dájú pé wọ́n á fetí sí ohùn rẹ,+ ìwọ àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì yóò lọ bá ọba Íjíbítì, ẹ ó sì sọ fún un pé, ‘Jèhófà Ọlọ́run àwọn Hébérù+ ti bá wa sọ̀rọ̀. Torí náà, jọ̀ọ́, jẹ́ ká rin ìrìn àjò ọjọ́ mẹ́ta lọ sí aginjù, ká lè rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run wa.’+

  • Ẹ́kísódù 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àmọ́ wọ́n sọ pé: “Ọlọ́run àwa Hébérù ti bá wa sọ̀rọ̀. Jọ̀ọ́, a fẹ́ rin ìrìn àjò ọjọ́ mẹ́ta lọ sí aginjù, ká sì rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run wa;+ àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, yóò fi àìsàn kọ lù wá tàbí kó fi idà pa wá.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́