-
1 Sámúẹ́lì 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Ṣebí mo ti ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà! Mo lọ jíṣẹ́ tí Jèhófà rán mi, mo mú Ágágì ọba Ámálékì wá, mo sì pa àwọn ọmọ Ámálékì run pátápátá.+
-