Sáàmù 139:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà. Jeremáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Kí n tó dá ọ nínú ìyá rẹ ni mo ti mọ̀* ọ́,+Kí wọ́n sì tó bí ọ* ni mo ti sọ ọ́ di mímọ́.*+ Mo fi ọ́ ṣe wòlíì àwọn orílẹ̀-èdè.”
16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà.
5 “Kí n tó dá ọ nínú ìyá rẹ ni mo ti mọ̀* ọ́,+Kí wọ́n sì tó bí ọ* ni mo ti sọ ọ́ di mímọ́.*+ Mo fi ọ́ ṣe wòlíì àwọn orílẹ̀-èdè.”