-
Ẹ́kísódù 13:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Mósè kó àwọn egungun Jósẹ́fù dání, torí Jósẹ́fù ti mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi òótọ́ inú búra pé: “Ó dájú pé Ọlọ́run ò ní gbàgbé yín. Kí ẹ kó egungun mi dání kúrò níbí.”+
-