6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+
36“Kí Bẹ́sálẹ́lì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Òhólíábù àti gbogbo ọkùnrin tó mọṣẹ́* tí Jèhófà ti fún ní ọgbọ́n àti òye kí wọ́n lè mọ bí wọ́n á ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ ìsìn mímọ́ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.”+