Ẹ́kísódù 28:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 “Kí o tún ṣe aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti ọ̀já fún àwọn ọmọ Áárónì+ pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n máa wé sórí, kí wọ́n lè ní ògo àti ẹwà.+ Léfítíkù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mósè mú àwọn ọmọ Áárónì sún mọ́ tòsí, ó wọ aṣọ fún wọn, ó so ọ̀já mọ́ wọn lára, ó sì wé* aṣọ sí wọn lórí,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.
40 “Kí o tún ṣe aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti ọ̀já fún àwọn ọmọ Áárónì+ pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n máa wé sórí, kí wọ́n lè ní ògo àti ẹwà.+
13 Mósè mú àwọn ọmọ Áárónì sún mọ́ tòsí, ó wọ aṣọ fún wọn, ó so ọ̀já mọ́ wọn lára, ó sì wé* aṣọ sí wọn lórí,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.