Ẹ́kísódù 37:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó fi ògidì wúrà ṣe ìbòrí.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+
6 Ó fi ògidì wúrà ṣe ìbòrí.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+