Nọ́ńbà 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jóṣúà+ ọmọ Núnì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Mósè láti kékeré fèsì pé: “Mósè olúwa mi, pa wọ́n lẹ́nu mọ́!”+ Diutarónómì 1:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Jóṣúà ọmọ Núnì, tó máa ń dúró níwájú rẹ+ ló máa wọ ilẹ̀ náà.+ Sọ ọ́ di alágbára,*+ torí òun ló máa mú kí Ísírẹ́lì jogún rẹ̀.”) Jóṣúà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Lẹ́yìn ikú Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà*+ ọmọ Núnì, ìránṣẹ́+ Mósè pé:
38 Jóṣúà ọmọ Núnì, tó máa ń dúró níwájú rẹ+ ló máa wọ ilẹ̀ náà.+ Sọ ọ́ di alágbára,*+ torí òun ló máa mú kí Ísírẹ́lì jogún rẹ̀.”)