-
Ẹ́kísódù 31:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kí ẹ pa Sábáàtì mọ́, torí ohun mímọ́ ló jẹ́ fún yín.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá sọ ọ́ di aláìmọ́. Tí ẹnikẹ́ni bá ṣiṣẹ́ kankan lọ́jọ́ náà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.+ 15 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ọjọ́ keje jẹ́ sábáàtì, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá.+ Ohun mímọ́ ló jẹ́ fún Jèhófà. Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣiṣẹ́ ní ọjọ́ Sábáàtì.
-