-
Léfítíkù 8:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Lẹ́yìn náà, Mósè gbà á lọ́wọ́ wọn, ó sì mú kí wọ́n rú èéfín lórí pẹpẹ lórí ẹbọ sísun. Wọ́n jẹ́ ẹbọ ìyannisípò tó ní òórùn dídùn.* Ọrẹ àfinásun sí Jèhófà ni.
-
-
Nọ́ńbà 6:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “‘Èyí ni òfin nípa Násírì: Tí ọjọ́ tó fi jẹ́ Násírì+ bá pé, kí ẹ mú un wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.
-
-
Nọ́ńbà 6:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí àlùfáà sì mú apá àgbò náà tí wọ́n bọ̀,+ kó mú búrẹ́dì aláìwú kan tó rí bí òrùka látinú apẹ̀rẹ̀ náà àti búrẹ́dì aláìwú pẹlẹbẹ kan, kó sì kó o lé àtẹ́lẹwọ́ Násírì náà lẹ́yìn tó ti gé àmì Násírì rẹ̀ kúrò.
-