ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 6:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Èyí ni ọrẹ tí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú wá fún Jèhófà ní ọjọ́ tí ẹ bá fòróró yàn wọ́n:+ ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,*+ kí wọ́n máa fi ṣe ọrẹ ọkà+ nígbà gbogbo, ààbọ̀ rẹ̀ ní àárọ̀, ààbọ̀ rẹ̀ ní alẹ́. 21 Kí o fi òróró yan án lórí agbada.+ Kí o pò ó mọ́ òróró dáadáa, yan ọrẹ ọkà náà, kí o sì mú un wá ní kéékèèké fún Jèhófà bí ọrẹ tó ní òórùn dídùn.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́