Sáàmù 141:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn. Òwe 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Má ṣe bá afiniṣẹ̀sín wí, torí á kórìíra rẹ.+ Bá ọlọ́gbọ́n wí, yóò sì nífẹ̀ẹ́ rẹ.+ Mátíù 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Bákan náà, tí arákùnrin rẹ bá ṣẹ̀, lọ sọ ẹ̀bi rẹ̀ fún un* láàárín ìwọ àti òun nìkan.+ Tó bá fetí sí ọ, o ti jèrè arákùnrin rẹ.+
5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn.
15 “Bákan náà, tí arákùnrin rẹ bá ṣẹ̀, lọ sọ ẹ̀bi rẹ̀ fún un* láàárín ìwọ àti òun nìkan.+ Tó bá fetí sí ọ, o ti jèrè arákùnrin rẹ.+