-
Nọ́ńbà 15:22-24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “‘Bó bá wá ṣẹlẹ̀ pé ẹ ṣe àṣìṣe, tí ẹ ò sì pa gbogbo àṣẹ yìí tí Jèhófà sọ fún Mósè mọ́, 23 gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún yín nípasẹ̀ Mósè láti ọjọ́ tí Jèhófà ti pàṣẹ àti jálẹ̀ àwọn ìran yín, 24 tó sì jẹ́ pé àṣìṣe ni, tí gbogbo àpéjọ náà ò sì mọ̀, kí gbogbo àpéjọ náà mú akọ ọmọ màlúù kan wá láti fi rú ẹbọ sísun tó máa mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà, pẹ̀lú ọrẹ ọkà rẹ̀ àti ọrẹ ohun mímu rẹ̀ bí ẹ ṣe máa ń ṣe é,+ pẹ̀lú ọmọ ewúrẹ́ kan láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.+
-