10 “‘Ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí* ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́.+ Àlejò èyíkéyìí tó wà lọ́dọ̀ àlùfáà tàbí alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́.
19 Gbogbo ọrẹ mímọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá mú wá fún Jèhófà+ ni mo ti fún ìwọ àti àwọn ọmọkùnrin rẹ àti àwọn ọmọbìnrin rẹ pẹ̀lú rẹ, kó jẹ́ ìpín+ yín títí lọ. Ó jẹ́ májẹ̀mú iyọ̀* tó máa wà títí lọ níwájú Jèhófà fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ pẹ̀lú rẹ.”