ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 18:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Mósè sọ fún bàbá ìyàwó rẹ̀ pé: “Torí pé àwọn èèyàn ń wá sọ́dọ̀ mi kí n lè bá wọn wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ Ọlọ́run ni. 16 Tí ẹjọ́ kan bá délẹ̀, wọ́n á gbé e wá sọ́dọ̀ mi, màá sì ṣèdájọ́ ẹnì kìíní àti ẹnì kejì, màá jẹ́ kí wọ́n mọ àwọn ìpinnu Ọlọ́run tòótọ́ àti àwọn òfin rẹ̀.”+

  • Nọ́ńbà 15:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà ní aginjù, wọ́n rí ọkùnrin kan tó ń ṣa igi ní ọjọ́ Sábáàtì.+

  • Nọ́ńbà 15:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Wọ́n sì fi sínú àhámọ́,+ torí òfin ò tíì sọ ohun tí wọ́n máa ṣe fún un.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́