Sáàmù 106:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Léraléra ló fi wọ́n lé àwọn orílẹ̀-èdè lọ́wọ́,+Kí àwọn tó kórìíra wọn lè ṣàkóso lé wọn lórí.+ Ìdárò 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn elénìní rẹ̀ ti wá di ọ̀gá* rẹ̀; àwọn ọ̀tá rẹ̀ kò sì ṣàníyàn.+ Jèhófà ti mú ẹ̀dùn ọkàn bá a nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tó pọ̀.+ Àwọn ọmọ rẹ̀ ti lọ sí oko ẹrú níwájú àwọn elénìní.+
5 Àwọn elénìní rẹ̀ ti wá di ọ̀gá* rẹ̀; àwọn ọ̀tá rẹ̀ kò sì ṣàníyàn.+ Jèhófà ti mú ẹ̀dùn ọkàn bá a nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tó pọ̀.+ Àwọn ọmọ rẹ̀ ti lọ sí oko ẹrú níwájú àwọn elénìní.+