ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:53
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 53 O sì máa wá jẹ àwọn ọmọ* rẹ, ẹran ara àwọn ọmọ rẹ lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fún ọ, torí bí nǹkan ṣe máa le tó nígbà tí wọ́n bá dó tì ọ́ àti torí wàhálà tí àwọn ọ̀tá rẹ máa kó bá ọ.

  • 2 Àwọn Ọba 6:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Torí náà, a se ọmọ mi, a sì jẹ ẹ́.+ Lọ́jọ́ kejì, mo sọ fún un pé, ‘Mú ọmọ rẹ wá kí a lè jẹ ẹ́.’ Àmọ́, ó fi ọmọ rẹ̀ pa mọ́.”

  • Jeremáyà 19:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Màá sì mú kí wọ́n jẹ ẹran ara àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọn, kálukú wọn á sì jẹ ẹran ara ọmọnìkejì rẹ̀, nítorí ogun tó dó tì wọ́n àti ìdààmú tó bá wọn nígbà tí àwọn ọ̀tá wọn àti àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí* wọn há wọn mọ́.”’+

  • Ìdárò 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn obìnrin aláàánú ti fọwọ́ ara wọn se àwọn ọmọ wọn. +

      Wọ́n ti di oúnjẹ ọ̀fọ̀ fún wọn nígbà tí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi wó lulẹ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 5:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “‘“Ṣe ni àwọn bàbá tó wà ní àárín yín yóò jẹ àwọn ọmọ wọn,+ àwọn ọmọ yóò sì jẹ àwọn bàbá wọn, màá ṣe ìdájọ́ yín, màá sì fọ́n àwọn tó ṣẹ́ kù nínú yín káàkiri.”’*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́