-
Jeremáyà 42:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Gbogbo àwọn tí ó fi dandan lé e pé àwọn yóò lọ máa gbé ní Íjíbítì ni idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn* yóò pa. Kò sí ẹnì kankan tó máa sá àsálà tàbí tó máa la àjálù tí màá mú bá wọn já.”’
-