-
Léfítíkù 14:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Àmọ́, tó bá jẹ́ aláìní, tí kò sì fi bẹ́ẹ̀ ní lọ́wọ́, kó mú ọmọ àgbò kan láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi, kó fi ṣe ọrẹ fífì, kó lè ṣe ètùtù fún ara rẹ̀, pẹ̀lú ìyẹ̀fun tó kúnná, tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,* tí wọ́n pò mọ́ òróró láti fi ṣe ọrẹ ọkà, òróró tó kún òṣùwọ̀n lọ́ọ̀gì kan,
-