-
Nọ́ńbà 1:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+
-
-
Nọ́ńbà 1:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 “Ẹ̀yà Léfì nìkan ni ìwọ kò gbọ́dọ̀ forúkọ wọn sílẹ̀, má sì kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ yòókù.
-