ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 13:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ.

  • Jẹ́nẹ́sísì 22:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.

  • Jẹ́nẹ́sísì 46:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó sọ pé: “Èmi ni Ọlọ́run tòótọ́, Ọlọ́run bàbá+ rẹ. Má bẹ̀rù láti lọ sí Íjíbítì, torí ibẹ̀ ni màá ti sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá.+

  • Ẹ́kísódù 38:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ìlàjì ṣékélì tó jẹ́ ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́* ni ìlàjì ṣékélì ẹnì kọ̀ọ̀kan, ìyẹn gbogbo ẹni tó wà lára àwọn tó forúkọ sílẹ̀ láti ẹni ogún (20) ọdún sókè,+ wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+

  • Nọ́ńbà 2:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Èyí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn; gbogbo àwọn tó wà nínú àwọn ibùdó tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́