-
Nọ́ńbà 1:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+
-
-
Nọ́ńbà 26:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún kan, ọgọ́rùn-ún méje àti ọgbọ̀n (601,730).+
-
-
Nọ́ńbà 26:64Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
64 Àmọ́ ìkankan nínú wọn kò sí lára àwọn tí Mósè àti àlùfáà Áárónì forúkọ wọn sílẹ̀ nígbà tí wọ́n ka iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní aginjù Sínáì.+
-