Léfítíkù 27:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Àmọ́, kí ẹnì kankan má ya àkọ́bí ẹran sí mímọ́, torí ti Jèhófà ni àkọ́bí tí ẹran bá bí.+ Ì báà jẹ́ akọ màlúù tàbí àgùntàn, Jèhófà ló ni ín.+
26 “‘Àmọ́, kí ẹnì kankan má ya àkọ́bí ẹran sí mímọ́, torí ti Jèhófà ni àkọ́bí tí ẹran bá bí.+ Ì báà jẹ́ akọ màlúù tàbí àgùntàn, Jèhófà ló ni ín.+