ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “‘Tó bá fẹ́ mú ẹran wá láti fi rú ẹbọ sísun látinú agbo ẹran,+ lára àwọn ọmọ àgbò tàbí àwọn ewúrẹ́, kó jẹ́ akọ tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá.+

  • Léfítíkù 1:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kó fi omi fọ ìfun àti ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì mú gbogbo rẹ̀ wá, kó sun ún lórí pẹpẹ kó lè rú èéfín. Ẹbọ sísun ni, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́