Léfítíkù 23:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “‘Kí ẹ ka sábáàtì méje láti ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì, láti ọjọ́ tí ẹ mú ìtí ọrẹ fífì+ náà wá. Kí ọjọ́ àwọn ọ̀sẹ̀ náà pé. 16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+
15 “‘Kí ẹ ka sábáàtì méje láti ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì, láti ọjọ́ tí ẹ mú ìtí ọrẹ fífì+ náà wá. Kí ọjọ́ àwọn ọ̀sẹ̀ náà pé. 16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+