Ẹ́kísódù 34:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Kí ẹ fi àwọn èso yín tó kọ́kọ́ pọ́n nígbà ìkórè àlìkámà* ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* nígbà tí ọdún bá yí po.+ Diutarónómì 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o wá fi ọrẹ àtinúwá tí o mú wá ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ kí o mú un wá bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá ṣe bù kún ọ tó.+ Ìṣe 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ọjọ́ Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì,+ gbogbo wọn wà níbì kan náà, bí àjọyọ̀ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́.
22 “Kí ẹ fi àwọn èso yín tó kọ́kọ́ pọ́n nígbà ìkórè àlìkámà* ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* nígbà tí ọdún bá yí po.+
10 Kí o wá fi ọrẹ àtinúwá tí o mú wá ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ kí o mú un wá bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá ṣe bù kún ọ tó.+