-
Léfítíkù 23:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ní ọjọ́ yìí, kí ẹ kéde+ àpéjọ mímọ́ fún ara yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa pa mọ́ títí lọ ni, ní gbogbo ibi tí ẹ̀ ń gbé.
-