Léfítíkù 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+ Léfítíkù 23:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí ẹ fi ọmọ ewúrẹ́ kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,+ kí ẹ sì fi akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì tí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀.+
16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+
19 Kí ẹ fi ọmọ ewúrẹ́ kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,+ kí ẹ sì fi akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì tí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀.+