-
Diutarónómì 32:48-50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+ 50 O máa kú sórí òkè tí o fẹ́ gùn yìí, a ó sì kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ,* bí Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe kú sórí Òkè Hóórì+ gẹ́lẹ́, tí wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,
-