ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 3:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Jẹ́ kí ẹ̀yà Léfì+ wá síwájú, kí o sì ní kí wọ́n dúró níwájú àlùfáà Áárónì, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́+ fún un. 7 Kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ wọn ní àgọ́ ìjọsìn, èyí ni ojúṣe wọn fún un àti fún gbogbo àpéjọ náà níwájú àgọ́ ìpàdé.

  • Nọ́ńbà 18:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Kí o tún mú àwọn arákùnrin rẹ tí wọ́n jẹ́ ara ẹ̀yà Léfì sún mọ́ tòsí, ẹ̀yà baba ńlá rẹ, kí wọ́n lè dara pọ̀ mọ́ ọ, kí wọn sì máa bá ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ṣiṣẹ́+ níwájú àgọ́ Ẹ̀rí.+ 3 Kí wọ́n máa ṣe ojúṣe wọn fún ọ àti fún àgọ́ náà lódindi.+ Àmọ́, wọn ò gbọ́dọ̀ sún mọ́ àwọn ohun èlò ibi mímọ́ àti pẹpẹ kí ẹ̀yin tàbí àwọn má bàa kú.+

  • 1 Kíróníkà 23:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Wọ́n tún ń ṣe ojúṣe wọn ní àgọ́ ìpàdé àti ní ibi mímọ́. Wọ́n sì ń ṣèrànwọ́ fún àwọn arákùnrin wọn, àwọn ọmọ Áárónì lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn ilé Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́