Nọ́ńbà 33:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Wọ́n wá kúrò ní Alimoni-díbílátáímù, wọ́n sì pàgọ́ sí àwọn òkè Ábárímù+ níwájú Nébò.+