Nọ́ńbà 32:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Átárótì, Díbónì, Jásérì, Nímírà, Hẹ́ṣíbónì,+ Éléálè, Sébámù, Nébò+ àti Béónì,+ 4 àwọn ilẹ̀ tí Jèhófà bá àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ ṣẹ́gun, dáa fún àwọn ẹran ọ̀sìn,+ ẹran ọ̀sìn àwa ìránṣẹ́ rẹ sì pọ̀ gan-an.”
3 “Átárótì, Díbónì, Jásérì, Nímírà, Hẹ́ṣíbónì,+ Éléálè, Sébámù, Nébò+ àti Béónì,+ 4 àwọn ilẹ̀ tí Jèhófà bá àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ ṣẹ́gun, dáa fún àwọn ẹran ọ̀sìn,+ ẹran ọ̀sìn àwa ìránṣẹ́ rẹ sì pọ̀ gan-an.”