Nọ́ńbà 11:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Wọ́n wá pe ibẹ̀ ní Kiburoti-hátááfà,*+ torí ibẹ̀ ni wọ́n sin àwọn èèyàn tó hùwà wọ̀bìà torí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn sí. Diutarónómì 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Bákan náà, ẹ tún múnú bí Jèhófà ní Tábérà,+ Másà+ àti ní Kiburoti-hátááfà.+
34 Wọ́n wá pe ibẹ̀ ní Kiburoti-hátááfà,*+ torí ibẹ̀ ni wọ́n sin àwọn èèyàn tó hùwà wọ̀bìà torí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn sí.