Ẹ́kísódù 23:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Màá pààlà fún yín láti Òkun Pupa dé òkun àwọn Filísínì àti láti aginjù dé Odò;*+ torí màá mú kí ọwọ́ yín tẹ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà, ẹ ó sì lé wọn kúrò níwájú yín.+ Jóṣúà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. Jóṣúà 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó tún lọ dé Ásímónì,+ títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ ààlà náà sì parí sí Òkun.* Èyí ni ààlà wọn lápá gúúsù.
31 “Màá pààlà fún yín láti Òkun Pupa dé òkun àwọn Filísínì àti láti aginjù dé Odò;*+ torí màá mú kí ọwọ́ yín tẹ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà, ẹ ó sì lé wọn kúrò níwájú yín.+
15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù.
4 Ó tún lọ dé Ásímónì,+ títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ ààlà náà sì parí sí Òkun.* Èyí ni ààlà wọn lápá gúúsù.