Nọ́ńbà 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+ Nọ́ńbà 26:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Torí Jèhófà ti sọ nípa wọn pé: “Ó dájú pé inú aginjù+ ni wọ́n máa kú sí.” Ẹnikẹ́ni ò ṣẹ́ kù lára wọn àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
65 Torí Jèhófà ti sọ nípa wọn pé: “Ó dájú pé inú aginjù+ ni wọ́n máa kú sí.” Ẹnikẹ́ni ò ṣẹ́ kù lára wọn àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+