-
Nọ́ńbà 26:54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Kí ẹ fi kún ogún tí ẹ máa pín fún àwùjọ tó bá pọ̀, kí ẹ sì dín ogún+ tí ẹ máa pín fún àwùjọ tó bá kéré kù. Bí iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ ní àwùjọ kọ̀ọ̀kan bá ṣe pọ̀ tó ni kí ogún wọn ṣe pọ̀ tó.
-