Nọ́ńbà 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Àkọ́bí gbogbo ohun alààyè,*+ tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko, yóò di tìrẹ. Àmọ́, o gbọ́dọ̀ ra àkọ́bí èèyàn+ pa dà, kí o sì tún ra àkọ́bí àwọn ẹran tó jẹ́ aláìmọ́ pa dà.+
15 “Àkọ́bí gbogbo ohun alààyè,*+ tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko, yóò di tìrẹ. Àmọ́, o gbọ́dọ̀ ra àkọ́bí èèyàn+ pa dà, kí o sì tún ra àkọ́bí àwọn ẹran tó jẹ́ aláìmọ́ pa dà.+