ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 3:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ojúṣe àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ nínú àgọ́ ìpàdé ni pé kí wọ́n máa bójú tó àgọ́ ìjọsìn àti àgọ́,*+ ìbòrí rẹ̀,+ aṣọ* tí wọ́n ta+ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, 26 àwọn aṣọ ìdábùú+ tí wọ́n ta sí àgbàlá, aṣọ* tí wọ́n ta+ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá tó yí àgọ́ ìjọsìn àti pẹpẹ ká, àwọn okùn àgọ́ rẹ̀ àti gbogbo iṣẹ́ tó jẹ mọ́ nǹkan wọ̀nyí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́