-
Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 ní ẹ̀yà Síméónì, Ṣẹ́lúmíẹ́lì+ ọmọ Súríṣádáì;
-