-
Nọ́ńbà 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kí wọ́n wá kó gbogbo ohun èlò+ tí wọ́n fi ń ṣiṣẹ́, èyí tí wọ́n máa ń lò déédéé nínú ibi mímọ́, kí wọ́n kó o sínú aṣọ aláwọ̀ búlúù, kí wọ́n fi awọ séálì bò ó, kí wọ́n sì gbé e sórí ọ̀pá gbọọrọ tí wọ́n á fi gbé e.
-