Diutarónómì 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára.+ Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì gbọ̀n rìrì níwájú wọn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń bá yín lọ. Kò ní pa yín tì, kò sì ní fi yín sílẹ̀.”+ Jóṣúà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+ Jóṣúà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+
6 Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára.+ Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì gbọ̀n rìrì níwájú wọn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń bá yín lọ. Kò ní pa yín tì, kò sì ní fi yín sílẹ̀.”+
6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+
9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+