-
Nọ́ńbà 13:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Kélẹ́bù wá gbìyànjú láti fi àwọn èèyàn náà lọ́kàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe dúró níwájú Mósè, ó sọ pé: “Ẹ jẹ́ ká gòkè lọ láìjáfara, ó dájú pé a máa gba ilẹ̀ náà, torí ó dájú pé a máa borí wọn.”+
-