-
Diutarónómì 11:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 tàbí ohun tó ṣe sí Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù ọmọ Rúbẹ́nì níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì, nígbà tí ilẹ̀ lanu tó sì gbé wọn mì pẹ̀lú agbo ilé wọn àti àwọn àgọ́ wọn àti gbogbo ohun alààyè tó tẹ̀ lé wọn.+
-
-
Sáàmù 106:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ni ilẹ̀ bá lanu, ó gbé Dátánì mì,
Ó sì bo àwọn tó kóra jọ sọ́dọ̀ Ábírámù.+
-