5 Ó sì sọ fún Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì í lẹ́yìn pé: “Tó bá di àárọ̀, Jèhófà máa jẹ́ ká mọ ẹni tó jẹ́ tirẹ̀+ àti ẹni tó jẹ́ mímọ́ àti ẹni tó gbọ́dọ̀ máa sún mọ́ ọn,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì yàn+ ló máa sún mọ́ ọn.
10 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Dá ọ̀pá+ Áárónì pa dà síwájú Ẹ̀rí, kó máa wà níbẹ̀, kó lè jẹ́ àmì+ fún àwọn ọmọ ọlọ̀tẹ̀,+ kí wọ́n má bàa kùn sí mi mọ́, kí wọ́n má bàa kú.”