2 Pétérù 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Wọ́n pa ọ̀nà tó tọ́ tì, a sì ti ṣì wọ́n lọ́nà. Wọ́n ṣe bíi ti Báláámù,+ ọmọ Béórì, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ èrè ìwà àìtọ́,+ Júùdù 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+
15 Wọ́n pa ọ̀nà tó tọ́ tì, a sì ti ṣì wọ́n lọ́nà. Wọ́n ṣe bíi ti Báláámù,+ ọmọ Béórì, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ èrè ìwà àìtọ́,+
11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+