ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 22:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Áńgẹ́lì Jèhófà wá sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi lu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ lẹ́ẹ̀mẹta yìí? Wò ó! Ṣe ni èmi fúnra mi jáde wá, kí n lè dí ọ lọ́nà, torí pé ohun tí o fẹ́ ṣe ta ko ohun tí mo fẹ́.+

  • 2 Pétérù 2:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Wọ́n pa ọ̀nà tó tọ́ tì, a sì ti ṣì wọ́n lọ́nà. Wọ́n ṣe bíi ti Báláámù,+ ọmọ Béórì, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ èrè ìwà àìtọ́,+ 16 àmọ́ a bá a wí torí ó ṣe ohun tí kò tọ́.+ Ẹran akẹ́rù tí kò lè sọ̀rọ̀ tó sọ̀rọ̀ bí èèyàn, kò jẹ́ kí wòlíì náà ṣe ohun tí kò bọ́gbọ́n mu.+

  • Ìfihàn 2:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Síbẹ̀, àwọn ohun kan wà tí mo rí tí ò ń ṣe tí kò dáa, àwọn kan wà láàárín yín tó ń tẹ̀ lé ẹ̀kọ́ Báláámù,+ ẹni tó kọ́ Bálákì+ pé kó fi ohun ìkọ̀sẹ̀ síwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n jẹ àwọn ohun tí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà, kí wọ́n sì ṣe ìṣekúṣe.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́