Nọ́ńbà 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, Jèhófà mú kí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà sọ̀rọ̀,*+ ó sì sọ fún Báláámù pé: “Kí ni mo ṣe fún ọ tí o fi ń lù mí lẹ́ẹ̀mẹta+ yìí?”
28 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, Jèhófà mú kí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà sọ̀rọ̀,*+ ó sì sọ fún Báláámù pé: “Kí ni mo ṣe fún ọ tí o fi ń lù mí lẹ́ẹ̀mẹta+ yìí?”