ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 22:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ó ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ sọ́dọ̀ Báláámù ọmọ Béórì ní Pétórì,+ èyí tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò* ní ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀. Ó sọ pé kí wọ́n pè é wá, ó ní: “Wò ó! Àwọn èèyàn kan ti wá láti Íjíbítì. Wò ó! Wọ́n bo ilẹ̀,*+ iwájú mi gan-an ni wọ́n sì ń gbé. 6 Torí náà, jọ̀ọ́ wá bá mi gégùn-ún+ fún àwọn èèyàn yìí, torí wọ́n lágbára jù mí lọ. Bóyá màá lè ṣẹ́gun wọn, kí n sì lé wọn kúrò ní ilẹ̀ náà, torí ó dá mi lójú pé ẹni tí o bá súre fún máa rí ìbùkún gbà, ègún sì máa wà lórí ẹni tí o bá gégùn-ún fún.”

  • Júùdù 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+

  • Ìfihàn 2:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Síbẹ̀, àwọn ohun kan wà tí mo rí tí ò ń ṣe tí kò dáa, àwọn kan wà láàárín yín tó ń tẹ̀ lé ẹ̀kọ́ Báláámù,+ ẹni tó kọ́ Bálákì+ pé kó fi ohun ìkọ̀sẹ̀ síwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n jẹ àwọn ohun tí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà, kí wọ́n sì ṣe ìṣekúṣe.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́