Jẹ́nẹ́sísì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ Jẹ́nẹ́sísì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù. Ìsíkíẹ́lì 27:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn igi ràgàjì* ti Báṣánì ni wọ́n fi ṣe àwọn àjẹ̀ rẹ,Igi sípírẹ́sì tí wọ́n fi eyín erin tẹ́ inú rẹ̀ láti àwọn erékùṣù Kítímù+ ni wọ́n fi ṣe iwájú ọkọ̀ rẹ.
6 Àwọn igi ràgàjì* ti Báṣánì ni wọ́n fi ṣe àwọn àjẹ̀ rẹ,Igi sípírẹ́sì tí wọ́n fi eyín erin tẹ́ inú rẹ̀ láti àwọn erékùṣù Kítímù+ ni wọ́n fi ṣe iwájú ọkọ̀ rẹ.